LYRICS

[LYRICS] "Ise Owo Re" – Victor Vincent Ft. Blessing Surulere

[Yoruba Praise chant to the Almighty God]

[BLESSING] Kabiesi iba re ooo
Ise owo re, gbin gbin nii
Mo roo ti ti, mii oku le roo tan
Oba to da orun, ti ofi opo gbe duro
Alapa nla to so ile aiye roo
Oba to da imole ti osi gba agbara lowo orun tabi osupa
Olulana, olutana, oludari aiye ati orun
Moma riii ise owo re o oluwa.

[VICTOR] Oba, oba
Oba aiye raiye, mori ise owo re (x2)
Iyin ati ope lo yee oo
Mori ise owo re(x2)

[BACKUPS] Oba, oba
Oba aiye raiye, mori ise owo re (x2)
Iyin ati ope lo yee oo
Mori ise owo re(x2)

MODULATION] (Call & Response)
VICTOR: Laiye lorun, haa kee hallelujah
BACK UPS: Aari ise owo re
(x4)

BRIDGE] BACK UP: Oba, awon oba
Mofi iyin fun oo nikan

[Yoruba Praise Chant to the Almighty God]

[BLESSING] Oba ti oro re ju ogun loo
Oba ari ibi, ri ogun, ri ala
Okan shosho ajanaku tii mii aiye ati orun
Oba tin fi eja se ile fun Jonah, to sii so di oko losi taasisi
Sebi Iwo noni olulana to Lana fun Elijah lati aiye yii lode orun
Awa ma gboriyin fun oruko ree oo
Ise owo re oni idiwon
Olulana, olutana, oludari aiye ati orun
Oba tin paaa agan lerin lojosi
Eni ipinle
Eni opin
Eni isaaju
Eni ikeyin
Eni ma gbori yin fun oruko re oooo

[VICTOR] Oba, oba
Oba aiye raiye, mori ise owo re (x2)
Iyin ati ope lo yee oo
Mori ise owo re (x2)

End

Click HERE to download ‘Ise Owo Re’ by Victor Vincent

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Random Bible verse

Can a mother forget the baby at her breast and have no compassion on the child she has borne? Though she may forget, I will not forget you! See, I have engraved you on the palms of my hands; your walls are ever before me.

LYRICS

More in LYRICS

Exit mobile version