Connect with us

UNCATEGORIZED

[LYRICS] “From Grass to Grace” – Tom Sax

O gbemi sórí èjìká rẹ (He put me on his shoulder)
O múmi gorí eshin (He put me on the horse)
From grass to grace lowa forí mise (He made my case be from grass to grace)
Elédùmarè mo dúpẹ́ orre (Mighty God i thank you for I thank you for your goodness)

O gbemi kúrò ní lodiba (He brought me out of lodiba )
O múmi gorí eshin (He put me on the horse)
From grass to grace lowa forí mise (He made my case be from grass to grace)
Elédùmarè mo dúpẹ́ orre (Mighty God i thank you for I thank you for your goodness)

O gbemi kúrò lasale (He put out of a barrel land)
O múmi lọ sílè tó da (He put me in a good land )
From grass to grace lowa forí mise (He made my case be from grass to grace)
Elédùmarè mo dúpẹ́ orre (Mighty God i thank you for I thank you for your goodness)

Nínú aginjù tí mo wà (In the wilderness where I am)
Ìrètí pín pátá (All hopes are lost)
Tebi tara lọ ti komi sílè (Family and brethrens have deserted me)
Ona àbáyọ kò tilè yọ (There was no way out)
Ayé wa ń bere pé Ọlọ́run mi da (People were asking Where’s my God)
Wọn ní ẹni tá daso fún ènìyàn laiye (they said who ever will help another must be capable of himself first)
Mowa gbójú sókè mo pe Olurun bàbá, Olorun ọmọ, ẹ̀mí mímọ́ (I then look up and called on God the Father, Son and Holy spirit)
Agbagba mẹ́rìnlélógún òde ọrùn (The 24 elders in heaven)
Wọn wá dide wọn wá gbejomiro laiye (They then arose and came to my rescue)
O gbemi sórí èjìká rẹ (He put me on his shoulder)
O múmi gorí eshin (He put me on the horse)
From grass to grace lowa forí mise (He made my case be from grass to grace)
Elédùmarè mo dúpẹ́ ore (Mighty God i thank you for I thank you for your goodness)

Ogbemi/3* kúrò ní lọdiba (He took me from lodiba)
Omu mi lọ sí afin (He took me to the Palace)
Ma wá wà pelu awon ọba alaiye (Am now with the Kings)
Èmi ti aba tá kafi ra àtùpà (a rejected person)
Ọwá sọmi di ajitanawo fún araiye (He made me an important person)
Mo di àgbàdo towa nínú ìgò (I became a corn in the bottle)
Adìẹ ń wo mi ò ń mọ mi lójú (The fowl kept gazing at me in dismay)
Ọpọlọ mi wá ń yan fanda (í became a from walking majestically)
Ní waju elegusi (in front of an egusi cooker
Elegusi olè yimi lata (egusi cooker could not ganish me with pepper)
From grass to grace lọ foro mi se (He made my case be from grass to grace)
Elédùmarè mo dúpẹ́ ọrẹ (Mighty God i thank you for your goodness)

Olorun kibati (God of sure target)/2*
Baba rere lose tèmi (Good father did mine)
Olorun to gbó àdúrà (God that answers prayers)
Olorun Atamatase (God of sure target)
Baba rere lose tèmi (Good father did mine)
Olórun Akindayomi (God of Akindayomi
Baba rere lose tèmi (Good father did mine)
Olurun Adeboye (God of Adeboye)
Baba rere lose tèmi (Good father did mine)
Ọlọ́run Ijo Ìràpadà (God of The Redeemed Christian Church of God)
Baba rere lose tèmi (good father did mine)
Olórun Adeagbo (God of Adeagbo)
Baba rere lose tèmi (good father did mine)
Ọlọ́run Sediraki, meshaki, Àbẹ́dínígò (God of Shadrach, Meshach and Abednego
Baba rere lose tèmi (good father did mine)
Ọlọ́run Mósè, Ọlọ́run Èlíjà, Ọlọ́run Jábẹ́ṣì (God of Moses, Elijah and Jabez)
Baba rere lose tèmi (good father did mine)
Ọlọ́run Àwọn ẹni mimo mimo to tí lo (God of the holy people that have gone)
Baba rere lose tèmi (good father did mine)

Click to comment

Leave a Reply

More in UNCATEGORIZED

%d bloggers like this: