LYRICS

[LYRICS] “Omo Oba” – Akeju Abosede (Absolute Grace)

Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ileri ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

[Lead singer] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ileri ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Eto rere olorun fun aiye mi koni ye rara o
nwo serere, nwo tai yo, nwo di olola laye
Aki re Omo oba, ka ma ri Dansaki re
Gbogbo ibiti mo ba de laye, nwo di eni itewogba
Nwo ko ni se aseti laye ti mo wa.
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

[Back ups] Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

[Lead singer] Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ileri ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Eto rere olorun fun aye mi, Koni ye rara o
Oro to ba ti enu Oluwa jade koni pada si rara
kama ri Oun to ti so, dandan ko se
ibiti to ti se eto, nwo de be laye mi
Ade ogo re, Ade Wura woni, nwo de laye,
nwo de Lorun, nwo ba Jesu Joba nunu ogo tuntun

[Back ups] Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

[Lead singer] Ibi mo ma de laye, dandan ni ma de be
Ite ogo ti enikeni ko Jo ko si ni iranmi
Itana ogo ti ko tan ri Lati Iran mi
Emi ni ti Iran mi reti to si ti farahan
Emi ni eni ashayan ti Oluwa ti da o
Emi ni eni ibukun, eni ogo, eni ara oto
Nwo tai yo, nwo tan, nwo lo ogo mi laye
Call: omo oba ni mi

[Back ups] Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

[Lead singer] Eni ba ri mi, oti ri Ola
eni ba ri mi , oti ri eyee
eni ba ri mi, odi alabukun fun
oun mo ba fi owo le
dandan ni ko se aseyori o
Nwo tai yo , nwo se rere
nwo di nla laye, nwo joko pelu awon oba Orilede
Omo oba ni mi
Hun o mu ayanmo mi se o laiye o

[Back ups] Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Random Bible verse

Live in harmony with one another. Do not be proud, but be willing to associate with people of low position. Do not be conceited.

LYRICS

More in LYRICS